Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Wọnú Ìsinmi Ọlọ́run!

Wọnú Ìsinmi Ọlọ́run!

HÉBÉRÙ 4:11

Àárọ̀

  • 9:40 Ohùn Orin

  • 9:50 Orin 87 àti Àdúrà

  • 10:00 Báwo La Ṣe Lè Wọnú Ìsinmi Ọlọ́run?

  • 10:15 Ṣé Lóòótọ́ ni “Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Wà Láàyè”?

  • 10:30 Jẹ́ Kí Jèhófà Máa Tọ́ Ẹ Sọ́nà

  • 10:55 Orin 89 àti Ìfilọ̀

  • 11:05 Jèhófà Máa Ń Bù Kún Àwọn Tó Bá Ń Ṣègbọràn

  • 11:35 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi

  • 12:05 Orin 32

Ọ̀sán

  • 1:20 Ohùn Orin

  • 1:30 Orin 49

  • 1:35 Ìrírí

  • 1:45 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́

  • 2:15 Àpínsọ Àsọyé: Wọ́n Ń Mú Inú Jèhófà Dùn!

    • • Àwọn Ọ̀dọ́

    • • Àwọn Arábìnrin

    • • Àwọn Àgbàlagbà

  • 3:00 Orin 38 àti Ìfilọ̀

  • 3:10 Wàá Láyọ̀ Bó O Ṣe Ń Sin Jèhófà

  • 3:55 Orin 118 àti Àdúrà