Friday
“Ìfẹ́ máa ń ní sùúrù”—1 Kọ́ríńtì 13:4
Àárọ̀
-
9:20 Fídíò Orin
-
9:30 Orin No. 66 àti Àdúrà
-
9:40 Ọ̀RỌ̀ ALÁGA: Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa “Ní Sùúrù”? (Jémíìsì 5:7, 8; Kólósè 1:9-11; 3:12)
-
10:10 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: “Ohun Gbogbo Ni Àkókò Wà Fún”
-
• Máa Ronú Nípa Bí Jèhófà Ṣe Máa Ń Fara Balẹ̀ Ṣe Nǹkan (Oníwàásù 3:1-8, 11)
-
• Ó Máa Ń Gba Àkókò Káwa Àtẹnì Kan Tó Di Ọ̀rẹ́ Tímọ́tímọ́ (Òwe 17:17)
-
• Ó Máa Ń Gba Àkókò Kí Òtítọ́ Tó Jinlẹ̀ Lọ́kàn Èèyàn (Máàkù 4:26-29)
-
• Ó Máa Ń Gba Àkókò Kọ́wọ́ Wa Tó Lè Tẹ Àfojúsùn Wa (Oníwàásù 11:4, 6)
-
-
11:05 Orin 143 àti Ìfilọ̀
-
11:15 BÍBÉLÌ KÍKÀ BÍ ẸNI ṢE ERÉ ÌTÀN: Dáfídì Fi Sùúrù Dúró De Jèhófà (1 Sámúẹ́lì 24:2-15; 25:1-35; 26:2-12; Sáàmù 37:1-7)
-
11:45 Ṣé O Mọyì Bí Sùúrù Ọlọ́run Ṣe Pọ̀ Tó? (Róòmù 2:4, 6, 7; 2 Pétérù 3:8, 9; Ìfihàn 11:18)
-
12:15 Orin 147 àti Àkókò Ìsinmi
Ọ̀sán
-
1:35 Fídíò Orin
-
1:45 Orin 17
-
1:50 Máa Ṣe Sùúrù Bíi ti Jésù (Hébérù 12:2, 3)
-
2:10 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Àwọn tí Jèhófà Bù Kún Torí Pé Wọ́n Ní Sùúrù
-
• Ábúráhámù àti Sérà (Hébérù 6:12)
-
• Jósẹ́fù (Jẹ́nẹ́sísì 39:7-9)
-
• Jóòbù (Jémíìsì 5:11)
-
• Módékáì àti Ẹ́sítà (Ẹ́sítà 4:11-16)
-
• Sekaráyà àti Èlísábẹ́tì (Lúùkù 1:6, 7)
-
• Pọ́ọ̀lù (Ìṣe 14:21, 22)
-
-
3:10 Orin 11 àti Ìfilọ̀
-
3:20 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Àwọn Nǹkan tí Jèhófà Dá Kọ́ Wa Pé Ó Máa Ń Ṣe Nǹkan Lásìkò
-
• Àwọn Ewéko (Mátíù 24:32, 33)
-
• Àwọn Ẹ̀dá Inú Òkun (2 Kọ́ríńtì 6:2)
-
• Àwọn Ẹyẹ (Jeremáyà 8:7)
-
• Àwọn Kòkòrò (Òwe 6:6-8; 1 Kọ́ríńtì 9:26)
-
• Àwọn Ẹranko (Oníwàásù 4:6; Fílípì 1:9, 10)
-
-
4:20 “Ẹ Ò Mọ Ọjọ́ Tàbí Wákàtí Náà” (Mátíù 24:36; 25:13, 46)
-
4:55 Orin 27 àti Àdúrà Ìparí