Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2024-2025 Tí Aṣojú Ẹ̀ka Ọ́fí ìsì Máa Bá Wa Ṣe

Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìhìn Rere Tì Ẹ́ Lójú

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn nǹkan tá a máa gbádùn ní àárọ̀ àti ọ̀sán àpéjọ àyíká tí aṣojú ẹ̀ka ọ́fí ìsì máa bá wa ṣe.

Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí

A máa dáhùn àwọn ìbéèrè yìí bá a ṣe ń bá àpéjọ náà lọ.