Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìhìn Rere Tì Ẹ́ Lójú

Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìhìn Rere Tì Ẹ́ Lójú

RÓÒMÙ 1:16

Àárọ̀

  • 9:40 Ohùn Orin

  • 9:50 Orin 67 àti Àdúrà

  • 10:00 Kí Nìdí Tí ‘Ìhìn Rere Ò Fi Tì Wá lójú?’

  • 10:15 Máa Fìgboyà Sọ Ohun Tó O Gbà Gbọ́

  • 10:30 Jẹ́ “Òṣìṣẹ́ Tí Kò Ní Ohunkóhun Tó Máa Tì Í Lójú”

  • 10:55 Orin 73 àti Ìfilọ̀

  • 11:05 Bá A Ṣe Lè Fi Hàn Pé A Ní Ẹ̀mí Agbára, Ìfẹ́ àti Àròjinlẹ̀

  • 11:35 Ìrìbọmi: Máa “Ṣègbọràn sí Ìhìn Rere”

  • 12:05 Orin 75

Ọ̀sán

  • 1:20 Ohùn Orin

  • 1:30 Orin 77

  • 1:35 Ìrírí

  • 1:45 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́

  • 2:15 Àpínsọ Àsọyé: A Ò Tijú . . .

    • • Àwọn Ìlànà Ọlọ́run

    • • Ìjọba Ọlọ́run

    • • Àwọn Tí Ọlọ́run Ń Lò Láti Bójú Tó Wa

  • 3:00 Orin 40 àti Ìfilọ̀

  • 3:10 “Máa Fi Jèhófà Yangàn”

  • 3:55 Orin 7 àti Àdúrà