Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí
1. Kí nìdí tí ìhìn rere ò fi tì wá lójú? (Róòmù 1:16; 11:13)
2. Báwo la ṣe lè sọ ohun tá a gbà gbọ́ láìbẹ̀rù? (Mát. 10:32; Róòmù 10:9)
3. Kí ló ń mú ká túbọ̀ já fáfá lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù? (2 Tím. 2:15)
4. Báwo la ṣe lè fara wé Ónẹ́sífórù? (2 Tím. 1:7, 8)
5. Báwo la ṣe lè fi hàn pé ojú ò tì wá láti ṣe ohun tí Jèhófà fẹ́? (Héb. 10:39; 1 Pét. 3:15; Jòh. 18:36; 1 Tẹs. 5:12, 13)
6. Báwo la ṣe ń “fi Jèhófà yangàn”? (Sm. 34:1, 2; 1 Kọ́r. 1:31)
© 2024 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
CA-brpgm25-YR