Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2024-2025 Tí Alábòójútó Àyíká Máa Bá Wa Ṣe

“Ẹ Máa Hùwà Lọ́nà Tó Yẹ Ìhìn Rere”

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn nǹkan tá a máa gbádùn ní àárọ̀ àti ọ̀sán àpéjọ àyíká tí alábòójútó àyíká máa bá wa ṣe.

Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí

A máa dáhùn àwọn ìbéèrè yìí bá a ṣe ń bá àpéjọ náà lọ.