Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

“Ẹ Máa Hùwà Lọ́nà Tó Yẹ Ìhìn Rere”

“Ẹ Máa Hùwà Lọ́nà Tó Yẹ Ìhìn Rere”

FÍLÍPÌ 1:27

Àárọ̀

  • 9:40 Ohùn Orin

  • 9:50 Orin 35 àti Àdúrà

  • 10:00 Báwo Ni Ìhìn Rere Ṣe Ń Jẹ́ Kí Ayé Wa Dáa Sí I?

  • 10:15 Àpínsọ Àsọyé: Ohun Tí Ìhìn Rere Mú Kí Wọ́n Ṣe

    • • Sítéfánù

    • • Fílípì

    • • Ákúílà àti Pírísílà

    • • Títù

  • 11:05 Orin 76 àti Ìfilọ̀

  • 11:15 Máa Tẹ̀ Síwájú Lẹ́nu “Iṣẹ́ Ìfọkànsin Ọlọ́run”

  • 11:35 Ìrìbọmi: Máa “Ṣègbọràn sí Ìhìn Rere”

  • 12:05 Orin 37

Ọ̀sán

  • 1:20 Ohùn Orin

  • 1:30 Orin 56 àti Àdúrà

  • 1:35 Àsọyé fún Gbogbo Èèyàn: Kí Ló Mú Kó O Gbà Pé Òótọ́ Lohun Tó O Gbà Gbọ́?

  • 2:05 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́

  • 2:35 Orin 24 àti Ìfilọ̀

  • 2:45 Àpínsọ Àsọyé: “À Ń Dámọ̀ràn Ara Wa Bí Òjíṣẹ́ Ọlọ́run . . . ”

    • • Tá A Bá Ní Ìfaradà

    • • Tá A Bá Jẹ́ Onínúure

    • • Tá A Bá Jẹ́ Olóòótọ́

  • 3:30 Báwo Ni Ìhìn Rere Ṣe Ń Kọ́ Wa?

  • 4:00 Orin 29 àti Àdúrà