Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí

Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí
  1. 1. Tá a bá gba ìhìn rere gbọ́, báwo ni ìyẹn ṣe máa mú kí ìwà wa dáa sí i? (Fílí. 1:27; 3:8)

  2. 2. Kí ni ìhìn rere ń mú ká ṣe? (Kól. 1:5, 6)

  3. 3. Kí ló ń jẹ́ kó wù wá láti máa wàásù ìhìn rere nìṣó? (2 Pét. 3:11, 12; 1 Kọ́r. 9:19, 23)

  4. 4. Báwo la ṣe lè dámọ̀ràn ara wa bí òjíṣẹ́ Ọlọ́run? (2 Kọ́r. 6:4-8)

  5. 5. Báwo ni ìhìn rere ṣe ń kọ́ wa? (Títù 2:11-14)

© 2024 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania

CA-copgm25-YR