Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Fifi Iwe Lọni

Fifi Iwe Lọni

Fifi Iwe Lọni

Nisinsinyi iwọ ti ṣàyẹ̀wò ọpọlọpọ awọn ẹkọ idi-ipilẹ pataki in Bibeli. Awa yoo gbà ọ niyanju lati maa bà a lọ lati maa dagba ninu imọ Ọrọ Ọlọrun. Awọn àrànṣe fun ọ bi o ti nṣe eyi niwọnyi:

Igbesi Aye Yii Ha Ni Gbogbo Ohun Ti O Wà Bi?

Mimu Ki Igbesi Ayè Idile Rẹ Jẹ Aláyọ

Igba Ewe Rẹ​—Bi O Ṣe Le Gbadun Rẹ Julọ

Awọn àrànṣe fun kikẹkọọ Bibeli wọnyi ni o lè ri gbà lọwọ awọn Elérii Jehofah ni agbegbe rẹ. Tabi ki o kọwe-beere fun wọn nipasẹ ifiweranṣẹ fun 2 (iye ọrẹ yi le yipada) ẹyọkan lati ọdọ Watch Tower Bible and Tract Society. (Lo addres ti ó wà ni oju-iwe ti ó tẹle e).