Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

A Tubọ Sọ Ete Ọlọrun Di Mimọ́

A Tubọ Sọ Ete Ọlọrun Di Mimọ́

A Tubọ Sọ Ete Ọlọrun Di Mimọ́

Lati mọ̀ si i nipa ete aiyeraiye Ọlọrun iranṣẹ bere fun iwe—

Otitọ Ti Nsinni Lọ Si Iye Aiyeraiye: iwe oloju-iwe 192, ti a fi páli ti o nipọn dì yi wà fun ikẹkọ Bibeli, ao si fi ranṣẹ si ọ bi o ba fi 35k pere ranṣẹ.

Alafia ati Ãbò Tõtọ—lati Orisun Wo?: Iwe yi ṣe alaye lọna ti o ṣe kedere awọn iṣoro ti o dojukọ iran enia eyiti o nfẹ atunṣe ki a ba le ni alafia ati ãbò. Awọn ilana Bibeli ti o nmu iyọrisi rere ati igbesi aiye alãbò wa li a ṣe ayẹwo le lori. Iwe ti ṣe ifọsiwẹwẹ idi abajọ awọn iṣoro ati pe o fi orisun na han ti alafia ati ábò tõtọ le gbà wá ninu iran wa yi.Kọwe si Watch Tower ni address eyikeyi ninu awọn ti o wà ni isalẹ yi: