Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú

Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú

Ọ̀rọ̀ Ìáájú

Awọn eniyan maa nsọ niye igba pe wọn nígbàgbọ́ ninu Mẹtalọkan, síbẹ̀ òye wọn nipa rẹ̀ yatọ.

Ki ni Mẹtalọkan naa jẹ́, níti gidi?

Bibeli ha fi kọ́ni bi?

Jesu Kristi ha ni Ọlọrun Olodumare tí ó sì jẹ́ apakan Mẹtalọkan naa bi?