Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Bí Iwọ Ba Le Walaaye Titilae Iwọ Yoo Ha Yàn Lati Ṣe Bẹẹ Bí?

Bí Iwọ Ba Le Walaaye Titilae Iwọ Yoo Ha Yàn Lati Ṣe Bẹẹ Bí?

Bí Iwọ Ba Le Walaaye Titilae Iwọ Yoo Ha Yàn Lati Ṣe Bẹẹ Bí?

Iwọ niti tootọ le walaaye titilae ninu Paradise ori ilẹ̀-ayé, bi ìwé pẹlẹbẹ yii ti fihan kedere. Ète Ọlọrun fun iru awọn ipo bẹẹ yoo ni imuṣẹ dajudaju! Ṣugbọn iwọ nilati yàn lati walaaye titilae.

Yíyàn yẹn, tí Jesu Kristi kọni, ni a gbọdọ gbekari ìmọ̀ pipeye nipa Ọlọrun. Ìwé pẹlẹbẹ yii ni a pese lati ran ọ lọwọ lati jere ìmọ̀ yẹn. Iranlọwọ siwaju sii ni o lè rí gbà lati ọdọ awọn Ẹlẹ́rìí Jehofa. Inu wọn yoo dun lati ṣe ikesini si ọdọ rẹ ni akoko ati ibi kan ti o rọrùn fun ọ. Bi iwọ yoo bá si fẹ́ lati tẹwọgba ikẹkọọ Bibeli kan ninu ilé lọfẹẹ, iwọ le sọ eyi di mímọ̀ nipa kikọwe si Watch Tower, P.M.B. 1090, Benin City, Edo State, tabi ni adirẹsi ti o ṣe wẹku nisalẹ yii.