Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Iwọ Le Walaaye Titilae Ninu Paradise Lori Ilẹ Aye

Iwọ Le Walaaye Titilae Ninu Paradise Lori Ilẹ Aye

Iwọ Le Walaaye Titilae Ninu Paradise Lori Ilẹ Aye

Wiwalaaye titilae ninu Paradise lori ilẹ-aye kii ṣe àlá kan lasan, gẹgẹ bi iwọ ti lè kíyèsí-mọ̀ daradara lẹhin kíkà iwe-pẹlẹbẹ ti nru ironu soke yii. Ṣugbọn ó yẹ ki o maa tẹsiwaju ninu imọ ti ẹmi yii. Iwe naa Iwọ Le Walaaye Titilae ninu Paradise lori Ilẹ Aye npese kíkárí lọna tí ó gbooro sii awọn kókó-ẹ̀kọ́ tí a ti gbeyẹwo ninu iwe-pẹlẹbẹ yii, ati awọn koko-ọran miiran tí ó yẹ ki a mọ̀ ki a lè gbadun iwalaaye ninu Paradise lori ilẹ-aye.