Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Má Ṣojo!

Má Ṣojo!

SÁÀMÙ 138:3

ÒWÚRỌ̀

  • 9:30 Ohùn Orin

  • 9:40 Orin 73 àti Àdúrà

  • 9:50 Jèhófà Ni Kì Í Jẹ́ Ká Ṣojo

  • 10:05 Àpínsọ Àsọyé: Jẹ́ Aláìṣojo Bíi Ti . . .

    • Énọ́kù

    • Mósè

    • Jèhóṣáfátì

    • Pétérù

  • 11:05 Orin 69 àti Ìfilọ̀

  • 11:15 Ẹ Mọ́kàn Le Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù

  • 11:30 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi

  • 12:00 Orin 48

Ọ̀SÁN

  • 1:10 Ohùn Orin

  • 1:20 Orin 63 àti Àdúrà

  • 1:30 Àsọyé fún Gbogbo Ènìyàn: Pinnu Pé Ìsìn Tòótọ́ Lo Máa Ṣe

  • 2:00 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́

  • 2:30 Orin 76 àti Ìfilọ̀

  • 2:40 Àpínsọ Àsọyé: Jẹ́ Aláìṣojo Bíi Ti Kristi Táwọn Èèyàn Bá Ń Fúngun Mọ́ Ẹ

    • Nínú Ìdílé

    • Nílé Ìwé

    • Níbi Iṣẹ́

    • Ní Àdúgbò

  • 3:40 Jèhófà Máa San Ẹ́ Lẹ́san “Ńláǹlà” Tó Ò Bá Ṣojo

  • 4:15 Orin 119 àti Àdúrà