Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Pẹ̀lú Gbogbo Ọkàn Rẹ

Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Pẹ̀lú Gbogbo Ọkàn Rẹ

DIUTARÓNÓMÌ 13:3

ÒWÚRỌ̀

  • 9:40 Ohùn Orin

  • 9:50 Orin 109 àti Àdúrà

  • 10:00 “Ohun Tí Ìfẹ́ Ọlọ́run Túmọ̀ Sí Nìyí”

  • 10:15 Jèhófà Là Ń Fìfẹ́ Hàn Sí Tá A Bá Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Ará Wa

  • 10:30 “Nífẹ̀ẹ́ Ọmọnìkejì Rẹ Bí Ara Rẹ”

  • 10:55 Orin 82 àti Ìfilọ̀

  • 11:05 “Ìfẹ́ Máa Ń Bo Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Ẹ̀ṣẹ̀ Mọ́lẹ̀”

  • 11:35 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi

  • 12:05 Orin 50

Ọ̀SÁN

  • 1:20 Ohùn Orin

  • 1:30 Orin 62

  • 1:35 Ìrírí

  • 1:45 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́

  • 2:15 Àpínsọ Àsọyé: Máa Yin Jèhófà Ní Gbogbo Ọjọ́ Ayé Rẹ

    • Ẹ̀yin Ọmọdé

    • Ẹ̀yin Ọ̀dọ́

    • Ẹ̀yin Àgbàlagbà

  • 3:00 Orin 10 àti Ìfilọ̀

  • 3:10 Fi Gbogbo Ọkàn Rẹ Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà

  • 3:55 Orin 37 àti Àdúrà