Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí

Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí
  1. Kí nìdí tí ìfẹ́ fi ṣe pàtàkì ju ìmọ̀ lọ? (1 Kọ́r. 8:1)

  2. Bíi táwọn ìránṣẹ́ Ọlọ́run láyé àtijọ́, báwo làwa náà ṣe lè gbé àwọn ará ró? (Róòmù 13:8)

  3. Báwo la ṣe lè fìfẹ́ hàn sáwọn tá a bá pàdé lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù? (1 Tẹs. 2:7, 8)

  4. Báwo la ṣe lè mú kí ìjọ máa dàgbà sí i? (Éfé. 4:1-3, 11-16; 1 Tẹs. 5:11)

  5. Báwo la ṣe lè máa fi ìfẹ́ ṣe gbogbo ohun tí a bá ń ṣe? (1 Kọ́r. 16:14)