Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

“Ìfẹ́ Ń Gbéni Ró”

“Ìfẹ́ Ń Gbéni Ró”

1 KỌ́RÍŃTÌ 8:1

ÒWÚRỌ̀

  • 9:30 Ohùn Orin

  • 9:40 Orin 90 àti Àdúrà

  • 9:50 “Ìmọ̀ Máa Ń Gbéra Ga, Àmọ́ Ìfẹ́ Ń Gbéni Ró”

  • 10:05 Àpínsọ Àsọyé: Wọ́n Gbé Àwọn Míì Ró

    • Bánábà

    • Pọ́ọ̀lù

    • Dọ́káàsì

  • 11:05 Orin 79 àti Ìfilọ̀

  • 11:15 Máa Fìfẹ́ Hàn Sáwọn Èèyàn Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù

  • 11:30 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi

  • 12:00 Orin 52

Ọ̀SÁN

  • 1:10 Ohùn Orin

  • 1:20 Orin 107 àti Àdúrà

  • 1:30 Àsọyé fún Gbogbo Ènìyàn: Báwo Ni Ìfẹ́ Tó Jinlẹ̀ Ṣe Ń Gbé Òtítọ́ Lárugẹ?

  • 2:00 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́

  • 2:30 Orin 101 àti Ìfilọ̀

  • 2:40 Àpínsọ Àsọyé: Mú Kí Ìjọ Máa Dàgbà Sí I

    • Nífẹ̀ẹ́ Òtítọ́ Bíbélì

    • Mọyì Ọgbọ́n Tó Wà Nínú Òfin Ọlọ́run

    • Máa Gbé Àwọn Ará Ró

  • 3:40 “Ẹ Máa Fi Ìfẹ́ Ṣe Gbogbo Ohun Tí Ẹ Bá Ń Ṣe”

  • 4:15 Orin 105 àti Àdúrà