Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí

Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí
  1. 1. Àwọn nǹkan mẹ́ta wo ni Jèhófà fún wa ká lè láyọ̀? (Sm. 32:1-10)

  2. 2. Kí lá jẹ́ kó o láyọ̀ nísinsìnyí? (Sm. 5:​11, 12; 91:14)

  3. 3. Kí lá jẹ́ ká láyọ̀ lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù láìka ìṣòro tá a lè máa kojú sí? (Ìṣe 13:50-52; Róòmù 5:3-5)

  4. 4. Kí la lè ṣe tá ò fi ní “di ẹrù pa” ọkàn wa, ká má bàa pàdánù ayọ̀ wa? (Lúùkù 21:34)

  5. 5. Báwo ni Jèhófà ṣe ń fún wa láyọ̀? (Sm. 92:4, 5)

  6. 6. Àwọn nǹkan wo ló yẹ ká ṣe tá a bá fẹ́ kí Jèhófà máa wà níwájú wa nígbà gbogbo? (Róòmù 1:20; Diu. 6:6-9; Fílí. 4:6; Sm. 16:3)