Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

“Máa Yọ̀ Nínú Jèhófà”

“Máa Yọ̀ Nínú Jèhófà”

Sáàmù 32:11

ÒWÚRỌ̀

  • 9:40 Ohùn Orin

  • 9:50 Orin 9 àti Àdúrà

  • 10:00 “Ẹ Máa Yọ̀ Nínú Jèhófà, Kí Inú Yín sì Máa Dùn”

  • 10:15 O Lè Láyọ̀ Bó O Tiẹ̀ Ní Ìṣòro

  • 10:30 Ẹ Máa Ní ‘Ìdùnnú Tó Kún Rẹ́rẹ́’ Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù

  • 10:55 Orin 76 àti Ìfilọ̀

  • 11:05 Ẹ Má Ṣe Jẹ́ Kí Ohunkóhun “Di Ẹrù Pa” Ọkàn Yín

  • 11:35 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi

  • 12:05 Orin 51

Ọ̀SÁN

  • 1:20 Ohùn Orin

  • 1:30 Orin 111

  • 1:35 Ìrírí

  • 1:45 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́

  • 2:15 Àpínsọ Àsọyé: Jèhófà Ń Mú Ká Láyọ̀

    • • Bá A Ṣe Ń Sọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn

    • • Bá A Ṣe Ń Ran Àwọn Ará Wa Lọ́wọ́

    • • Bá A Ṣe Ń Fara Da Ìṣòro

  • 3:00 Orin 2 àti Ìfilọ̀

  • 3:10 Jẹ́ Kí Jèhófà Máa Wà Níwájú Rẹ Nígbà Gbogbo

  • 3:55 Orin 7 àti Àdúrà