Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2020-2021​—Tí Alábòójútó Àyíká Máa Bá Wa Ṣe

Wo ìtòlẹ́sẹẹsẹ àpéjọ àyíká yìí, kó o sì máa fọkàn bá a lọ. Àkòrí àpéjọ yìí ni “Mú Ọkàn Jèhófà Yọ̀!”

Mú Ọkàn Jèhófà Yọ̀!

Àwọn ohun tá a máa gbádùn láàárọ̀ àti ọ̀sán ọjọ́ àpéjọ àyíká tí alábòójútó àyíká máa bá wa ṣe ló wà nínú ìwé yìí.

Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí

A máa dáhùn àwọn ìbéèrè yìí nígbà tí àpéjọ náà bá ń lọ lọ́wọ́.