Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí

Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí
  1. 1. Àǹfààní wo làwa ìránṣẹ́ Jèhófà ní? (Òwe 27:11)

  2. 2. Báwo la ṣe lè fìwà jọ Jésù, ká sì múnú Jèhófà dùn? (Jòh. 8:29)

  3. 3. Báwo la ṣe lè múnú Jèhófà dùn lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù? (Jòh. 15:8)

  4. 4. Báwo la ṣe lè máa múnú Jèhófà dùn ní gbogbo apá ìgbésí ayé wa? (Jòh. 14:31; Éfé. 6:1-4; Sm. 35:18; 1 Pét. 2:12)

  5. 5. Báwo la ṣe lè borí ìṣòro, ìrẹ̀wẹ̀sì àti àdánwò? (Neh. 8:10)