Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Mú Ọkàn Jèhófà Yọ̀!

Mú Ọkàn Jèhófà Yọ̀!

Òwe 27:11

ÒWÚRỌ̀

  • 9:30 Ohùn Orin

  • 9:40 Orin 29 àti Àdúrà

  • 9:50 Mú Ọkàn Jèhófà Yọ̀!

  • 10:05 Àpínsọ Àsọyé: Fìwà Jọ Jèhófà Láwọn Ọ̀nà Pàtàkì Yìí

    • • Ó Jẹ́ Onídàájọ́ Òdodo

    • • Ó Jẹ́ Alágbára

    • • Ó Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n

    • • Ó Jẹ́ Onífẹ̀ẹ́

  • 11:05 Orin 81 àti Ìfilọ̀

  • 11:15 Máa “So Èso Púpọ̀” Kó O Lè Fògo fún Ọlọ́run

  • 11:30 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi

  • 12:00 Orin 49

Ọ̀SÁN

  • 1:10 Ohùn Orin

  • 1:20 Orin 28 àti Àdúrà

  • 1:30 Àsọyé fún Gbogbo Èèyàn: Bí O Ṣe Lè Mú Ọkàn Ọlọ́run Yọ̀

  • 2:00 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́

  • 2:30 Orin 35 àti Ìfilọ̀

  • 2:40 Àpínsọ Àsọyé: Máa Ṣe Ohun Tí Inú Jèhófà Dùn Sí . . .

    • • Ní Ìgbésí Ayé Rẹ

    • • Nínú Ìdílé Rẹ

    • • Nínú Ìjọ Rẹ

    • • Ní Àdúgbò Rẹ

  • 3:40 “Ìdùnnú Jèhófà Ni Agbára Yín”

  • 4:15 Orin 110 àti Àdúrà