Aájò Àlejò TẸ̀ Ẹ̣́ Aájò Àlejò Ro 12:13; Heb 13:2; 1Pe 4:9 Tún wo 1Ti 3:2; Tit 1:8 Àpẹẹrẹ inú Bíbélì: Jẹ 18:1-8—Ábúráhámù àti Sérà ṣe àwọn áńgẹ́lì lálejò Iṣe 16:13-15—Lìdíà rọ àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù àtàwọn tó ń bá a rìnrìn àjò pé kí wọ́n wá sílé òun, kóun lè ṣe wọ́n lálejò Pa Dà Èyí Tó Kàn O Tún Lè Wo JÉSÙ—Ọ̀NÀ, ÒTÍTỌ́ ÀTI ÌYÈ Ẹ̀kọ́ Nípa Aájò Àlejò àti Àdúrà Jésù lọ kí Màríà àti Màtá nílé wọn. Kí ló kọ́ wọn nípa aájò àlejò? Báwo ló sì ṣe kọ́ wọn ní ohun tó yẹ kí wọ́n máa gbàdúrà fún lẹ́yìn náà? ILÉ ÌṢỌ́ Inú Rere Ṣe Pàtàkì Lójú Ọlọ́run Ṣé ó yẹ kó o máa fi inú rere hàn sí gbogbo èèyàn. Ojú wo ni Ọlọ́run fi ń wo ànímọ́ yìí? KẸ́KỌ̀Ọ́ LỌ́DỌ̀ OLÙKỌ́ ŃLÁ NÁÀ Bí A Ṣe Lè Ní Ayọ̀ Olùkọ́ Ńlá náà jẹ́ ká mọ àṣírí pàtàkì kan. NÍPA WA Ṣé O Fẹ́ Ká Wá Ẹ Wá O lè mọ̀ sí i nípa Bíbélì tàbí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà. Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Aájò Àlejò ÀWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ TÓ LÈ RAN ÀWA KRISTẸNI LỌ́WỌ́ Aájò Àlejò Yorùbá Aájò Àlejò https://assetsnffrgf-a.akamaihd.net/assets/ct/1add6d1d93/images/syn_placeholder_sqr.png scl ojú ìwé 10