Àwọn Àna
Tí ọkùnrin àti obìnrin kan bá ṣègbéyàwó, kí nìdí tí kò fi yẹ káwọn òbí àtàwọn àna máa tojú bọ ohun tó ń lọ nínú ìdílé wọn?
Tún wo Sm 34:14; Mt 5:9; Ro 12:18; 14:10-13
Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:
Ẹk 18:1-27—Mósè àti Jẹ́tírò tó jẹ́ bàbá ìyàwó ẹ̀ bọ̀wọ̀ fún ara wọn