Àwọn Kristẹni
Báwo ló ṣe di pé à ń pé àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jésù ní Kristẹni?
Kí la fi ń dá àwọn Kristẹni tòótọ́ mọ̀?
Báwo ni Ọlọ́run ṣe gba àwọn Kristẹni tòótọ́ là?
Kí nìdí táwa Kristẹni fi gbà pé Kristi ni ọba wa tá a sì tún ń tẹrí ba fún un?
Kí nìdí táwa Kristẹnì tòótọ́ kì í fi í ṣe apá kan ayé?
Kí nìdí táwa Kristẹni tòótọ́ fi ń tẹ̀ lé òfin ìjọba?
Ro 13:1, 6, 7; Tit 3:1; 1Pe 2:13, 14
-
Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:
-
Mt 22:15-22—Jésù sọ ìdí tó fi yẹ káwọn ọmọ ẹ̀yìn ẹ̀ máa san owó orí
-
Iṣe 4:19, 20; 5:27-29—Àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jésù fi hàn pé àwọn ṣe tán láti máa tẹ̀ lé òfin ìjọba tí kò bá ṣàá ti ta ko òfin Ọlọ́run
-
Ọ̀nà wo làwa Kristẹni gbà jẹ́ ọmọ ogun?
Tún wo Ef 6:12, 13; 1Ti 1:18
Kí nìdí tó fi yẹ kí ìwà àwa Kristẹni bá ohun tá à ń kọ́ mu?
Tún wo Ef 4:17, 19-24; Jem 3:13
-
Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:
-
Iṣe 9:1, 2; 19:9, 23—Ìgbà kan wà tí wọ́n ń pe ẹ̀sìn Kristẹni ní “Ọ̀nà Náà,” èyí jẹ́ ká rí i pé ó gbọ́dọ̀ hàn nínú gbogbo ohun tá à ń ṣe pé ọmọ ẹ̀yìn Kristi ni wá
-
Kí nìdí tó fi yẹ káwa Kristẹni tòótọ́ jẹ́ Ẹlẹ́rìí fún Jèhófà Ọlọ́run?
Ais 43:10, 12; Jo 17:6, 26; Ro 15:5, 6; Ifi 3:14
Tún wo Heb 13:15
Kí nìdí tó fi yẹ káwa Kristẹni tòótọ́ tún máa jẹ́rìí nípa Jésù Kristi?
Kí nìdí tó fi yẹ kí gbogbo Kristẹni tòótọ́ máa wàásù ìhìn rere?
Ṣé ó yẹ káwa Kristẹni máa bẹ̀rù inúnibíni?
Wo “Inúnibíni”
Ṣé gbogbo Kristẹni tòótọ́ ló máa lọ bá Jésù Kristi jọba lọ́run?
Tún wo 1Pe 1:3, 4
Ibo ni èyí tó pọ̀ jù lára àwọn Kristẹni tòótọ́ ti máa gbádùn ìyè àìnípẹ̀kun?
Ṣé a lè rí Kristẹni tòótọ́ nínú àwọn ẹ̀sìn tó ń pera wọn ní Kristẹni lónìí?
Ṣé gbogbo àwọn tó ń pera wọn ní Kristẹni ni ọmọlẹ́yìn Jésù lóòótọ́?
Mt 7:21-23; Ro 16:17, 18; 2Kọ 11:13-15; 2Pe 2:1
-
Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:
-
Mt 13:24-30, 36-43—Jésù sọ àpéjúwe kan tó fi hàn pé àwọn ayédèrú Kristẹni máa pọ̀
-
2Kọ 11:24-26—Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù sọ pé “àwọn èké arákùnrin” wà lára àwọn tó mú kí nǹkan nira fóun
-
1Jo 2:18, 19—Àpọ́sítélì Jòhánù kìlọ̀ pé “ọ̀pọ̀ aṣòdì sí Kristi” ló ti kúrò nínú òtítọ́
-