Ayọ̀
Báwo la ṣe mọ̀ pé Ọlọ́run aláyọ̀ ni Jèhófà?
Àwọn nǹkan wo ló lè mú ká máa láyọ̀?
Sm 100:2; Onw 8:15; Ais 65:14, 18; Flp 4:1, 4
Tún wo Sm 64:10; Ais 61:10; Mt 5:11, 12
-
Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:
-
Sm 16:7-9, 11—Ọba Dáfídì ní àjọṣe tó dáa pẹ̀lú Jèhófà, ìyẹn sì mú kó láyọ̀ tó pọ̀
-
Heb 12:1-3—Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù sọ pé tá a bá tiẹ̀ níṣòro tó le gan-an, a ṣì lè máa láyọ̀ bíi ti Jésù tá a bá ń ronú lórí ìrètí tá a ní
-