Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ìdúróṣinṣin

Ìdúróṣinṣin

Sm 18:25; Lk 1:74, 75; Ef 4:24; Ifi 15:4

Tún wo Sm 116:15; 145:17

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Rut 1:16, 17; 3:10—Rúùtù pinnu pé òun máa jẹ́ adúróṣinṣin sí Náómì àti sí Jèhófà

    • 2Ọb 2:1, 2, 4, 6—Èlíṣà fi hàn pé òun jẹ́ adúróṣinṣin, torí ó pinnu pé òun ò ní fi wòlíì Èlíjà sílẹ̀