Ìfòyebánilò
Kí nìdí tó fi yẹ káwa Kristẹni máa fòye báni lò?
Tún wo 1Ti 3:2, 3
-
Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:
-
Jẹ 18:23-33—Jèhófà ní sùúrù fún Ábúráhámù nígbà tó ń bi í ní ìbéèrè nípa ìparun Sódómù àti Gòmórà
-
Jẹ 19:16-22, 30—Lọ́ọ̀tì ní kí Jèhófà jẹ́ kóun sá lọ sí Sóárì dípò tóun á fi sá lọ sí agbègbè olókè, Jèhófà sì gbà kó ṣe bẹ́ẹ̀ torí pé Jèhófà máa ń fòye báni lò
-
Mt 15:21-28—Jésù fi hàn pé òun máa ń fòye báni lò, ó ṣe ohun tí obìnrin ará Foníṣíà kan béèrè nígbà tó rí i pé obìnrin náà ní ìgbàgbọ́ tó lágbára
-