Ìkóra-Ẹni-Níjàánu
Báwo ni Jèhófà ṣe fi hàn pé òun máa ń kó ara òun níjàánu?
Àwọn apá wo nínú ìgbésí ayé wa ló ti yẹ ká máa kó ara wa níjàánu?
Owe 16:32; 25:28; 1Kọ 9:25, 27
Tún wo 2Ti 2:23-25; Tit 1:7, 8
Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:
2Sa 16:5-14—Ọba Dáfídì kó ara ẹ̀ níjàánu nígbà tí Ṣíméì ń ṣépè fún un, tó sì ń sọ̀rọ̀ àbùkù sí i
1Pe 2:21-23—Àpọ́sítélì Pétérù sọ bí Jésù ṣe kó ara ẹ̀ níjàánu lọ́nà tó lágbára nígbà táwọn èèyàn ń sọ̀rọ̀ àbùkù sí i, tí wọ́n sì ń fìyà jẹ ẹ́
Kí ló máa ràn wá lọ́wọ́ ká lè túbọ̀ máa kó ara wa níjàánu?
Lk 11:9-13; Ga 5:22, 23; Ef 4:23, 24; Kol 4:2
Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:
Lk 11:5-8—Jésù jẹ́ ká mọ bó ti ṣe pàtàkì tó pé ká má ṣe jẹ́ kó sú wa láti máa bẹ Jèhófà pé kó ràn wá lọ́wọ́