Jẹ́ Olóòótọ́
Di 25:13-16; 2Kọ 8:21; Ef 4:25; Heb 13:18
Tún wo Job 6:25; Owe 3:32; 6:16-19; 2Kọ 6:3, 4, 7, 8
Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:
Sm 15:1-5—Jèhófà sọ àwọn nǹkan tẹ́ni tó bá fẹ́ jẹ́ ọ̀rẹ́ ẹ̀ tímọ́tímọ́ gbọ́dọ̀ máa ṣe, lára ẹ̀ ni pé ẹni náà gbọ́dọ̀ jẹ́ olóòótọ́
Iṣe 5:1-10—Ananáyà àti Sàfírà kò sọ òótọ́, wọ́n sì jìyà ohun tí wọ́n ṣe