Ọ̀làwọ́
Owe 11:25; Iṣe 20:35; 2Kọ 9:11
Tún wo Owe 19:17; Mt 10:8; Lk 6:38
Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:
1Kr 22:6-16—Ó dùn Dáfídì gan-an pé òun ò láǹfààní láti kọ́ tẹ́ńpìlì, síbẹ̀ ó fi tinútinú ṣètìlẹyìn fún iṣẹ́ kíkọ́ tẹ́ńpìlì náà
1Ọb 17:8-16—Oúnjẹ díẹ̀ tí opó Sáréfátì àti ọmọ ẹ̀ máa jẹ ni wọ́n ní, síbẹ̀ opó náà fún wòlíì Èlíjà lóúnjẹ