Ọ̀rẹ́
Àwọn wo ló ṣe pàtàkì jù tó yẹ ká mú lọ́rẹ̀ẹ́?
Sm 25:14; Jo 15:13-15; Jem 2:23
Tún wo Owe 3:32
-
Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:
-
Jẹ 5:22-24—Énọ́kù sún mọ́ Ọlọ́run gan-an
-
Jẹ 6:9—Nóà náà bá Ọlọ́run rìn bíi ti baba ńlá ẹ̀, Énọ́kù
-
Kí nìdí tá a fi nílò àwọn ọ̀rẹ́ tòótọ́?
Owe 13:20; 17:17; 18:24; 27:17
Tún wo Owe 18:1
Kí nìdí tó fi yẹ ká máa pé jọ déédéé pẹ̀lú àwọn tá a jọ ń sin Jèhófà?
Báwo la ṣe lè jẹ́ ọ̀rẹ́ tòótọ́, ká sì tún ní àwọn ọ̀rẹ́ tòótọ́?
Kí nìdí tó fi léwu láti máa bá àwọn tí kò nífẹ̀ẹ́ Jèhófà ṣọ̀rẹ́?
Owe 13:20; 1Kọ 15:33; Ef 5:6-9
Tún wo 1Pe 4:3-5; 1Jo 2:15-17
Tún wo “Bíbá Ayé Ṣọ̀rẹ́”
-
Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:
-
Jẹ 34:1, 2—Dínà jìyà torí pé àwọn èèyàn burúkú ló mú lọ́rẹ̀ẹ́
-
2Kr 18:1-3; 19:1, 2—Jèhófà bá Ọba Jèhóṣáfátì wí torí pé ó bá Áhábù tó jẹ́ ọba búburú ṣọ̀rẹ́
-
Ṣó yẹ ká yẹra pátápátá fún àwọn tí kò sin Jèhófà?
Kí nìdí tí kò fi yẹ ká fẹ́ ẹni tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà?
Wo “Ìgbéyàwó”
Kí nìdí tí kò fi yẹ ká ní ohunkóhun ṣe pẹ̀lú àwọn tí wọ́n ti yọ kúrò nínú ìjọ?