Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀPÓTÍ Ẹ̀KỌ́ 22A

Ìdánwò Ìkẹyìn Tí Aráyé Máa Dojú Kọ

Ìdánwò Ìkẹyìn Tí Aráyé Máa Dojú Kọ
  • Àwọn Èèyàn Á Di Ẹni Pípé​—1 KỌ́R. 15:26

  • Jésù Dá Ìjọba Pa Dà fún Jèhófà​—1 KỌ́R. 15:24

  • A Tú Sátánì Sílẹ̀ Kúrò Nínú Ọ̀gbun Àìnísàlẹ̀; Àwọn Ọlọ̀tẹ̀ Dara Pọ̀ Mọ́ Sátánì Láti Jagun Àjàkẹ́yìn​—ÌFI. 20:3, 7, 8

  • Gbogbo Àwọn Ọlọ̀tẹ̀ Pa Run​—ÌFI. 20:9, 10, 15

  • Ìyè Àìnípẹ̀kun Nínú Ayé Tuntun Tí Ìṣọ̀kan àti Àlàáfíà Ti Ń Jọba​—RÓÒMÙ 8:19-21