Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀPÓTÍ Ẹ̀KỌ́ 10A

Ìjọsìn Mímọ́​—Pa Dà Bọ̀ Sípò Díẹ̀díẹ̀

Ìjọsìn Mímọ́​—Pa Dà Bọ̀ Sípò Díẹ̀díẹ̀
  • ‘Ariwo tó dà bí ìgbà tí nǹkan ń rọ́ gììrì’

    William Tyndale àtàwọn míì túmọ̀ Bíbélì sí èdè Gẹ̀ẹ́sì àtàwọn èdè míì

  • “Iṣan àti ẹran”

    Charles T. Russell àtàwọn alábàákẹ́gbẹ́ rẹ̀ mú káwọn èèyàn lóye òtítọ́ Bíbélì

  • “Wọ́n wá di alààyè, wọ́n sì dìde dúró”

    Lẹ́yìn táwọn èèyàn Jèhófà “di alààyè” lọ́dún 1919, wọ́n túbọ̀ tẹra mọ́ iṣẹ́ ìwàásù wọn