Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀPÓTÍ Ẹ̀KỌ́ 9A

Jèhófà Mú Àwọn Ìlérí Rẹ̀ Ṣẹ​—Nígbà Àtijọ́

Jèhófà Mú Àwọn Ìlérí Rẹ̀ Ṣẹ​—Nígbà Àtijọ́
  • 1. Kò ní sí ìbọ̀rìṣà nínú ìjọsìn mímọ́

  • 2. Wọ́n á pa dà sí ilẹ̀ tó lọ́ràá

  • 3. Jèhófà máa tẹ́wọ́ gba àwọn ọrẹ

  • 4. Àwọn ọkùnrin olóòótọ́ máa múpò iwájú

  • 5. Wọ́n á jọ́sìn Ọlọ́run níṣọ̀kan nínú tẹ́ńpìlì