Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀPÓTÍ Ẹ̀KỌ́ 11A

Díẹ̀ Lára Àwọn Olùṣọ́ Tó Jẹ́ Àpẹẹrẹ Rere

Díẹ̀ Lára Àwọn Olùṣọ́ Tó Jẹ́ Àpẹẹrẹ Rere

Àwọn olùṣọ́ yìí kojú àtakò, wọ́n jẹ́ adúróṣinṣin, wọ́n sì kéde ìhìn rere àti ìkìlọ̀ látọ̀dọ̀ Ọlọ́run.

ÍSÍRẸ́LÌ ÀTIJỌ́

  • Àìsáyà 778 sí n. 732 Ṣ.S.K.

  • Jeremáyà 647 sí 580 Ṣ.S.K.

  • Ìsíkíẹ́lì 613 sí n. 591 Ṣ.S.K.

ỌGỌ́RÙN-ÚN ỌDÚN KÌÍNÍ

  • Jòhánù Arinibọmi 29 sí 32 S.K.

  • Jésù 29 sí 33 S.K.

  • Pọ́ọ̀lù n. 34 sí n. 65 S.K.

ÒDE ÒNÍ

  • C. T. Russell àti Àwọn Alábàákẹ́gbẹ́ Rẹ̀ n. 1879 sí 1919

  • Ẹrú Olóòótọ́ 1919 Títí Dòní