Friday
“Ẹ má ṣe jẹ́ kí a juwọ́ sílẹ̀ ní ṣíṣe ohun tí ó dára lọ́pọ̀lọpọ̀” —GÁLÁTÍÀ 6:9
ÒWÚRỌ̀
-
8:20 [8:20]* Fídíò Orin
-
8:30 [8:30] Orin 77 àti Àdúrà
-
8:40 [8:40] Ọ̀RỌ̀ ALÁGA: A Ò Gbọ́dọ̀ Sọ̀rètí Nù Lákòókò Tá A Wà Yìí! (Ìṣípayá 12:12)
-
9:15 [9:15] ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Máa Wàásù Nìṣó “Láìdábọ̀”
-
Lọ́nà Àìjẹ́-Bí-Àṣà (Ìṣe 5:42; Oníwàásù 11:6)
-
Láti Ilé-Dé-Ilé (Ìṣe 20:20)
-
Níbi Térò Pọ̀ Sí (Ìṣe 17:17)
-
Máa Sọ Àwọn Èèyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn (Róòmù 1:14-16; 1 Kọ́ríńtì 3:6)
-
-
10:05 [10:05] Orin 76 àti Ìfilọ̀
-
10:15 [10:15] BÍBÉLÌ KÍKÀ BÍ ẸNI ṢE ERÉ ÌTÀN: Jèhófà Máa Ń Gba Àwọn Èèyàn Rẹ̀ Sílẹ̀ (Ẹ́kísódù 3:1-22; 4:1-9; 5:1-9; 6:1-8; 7:1-7; 14:5-10, 13-31; 15:1-21)
-
[10:45] ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Kọ́ Ilé Tó Máa Wà Pẹ́ Títí
-
“Ní Ìtẹ́lọ́rùn Pẹ̀lú Àwọn Nǹkan Ìsinsìnyí” (Hébérù 13:5; Sáàmù 127:1, 2)
-
Dáàbò Bo Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ “Ohun Tí Ó Jẹ́ Ibi” (Róòmù 16:19; Sáàmù 127:3)
-
Ẹ Tọ́ Àwọn Ọmọ Yín ‘Ní Ọ̀nà Tí Wọn Yóò Tọ̀’ (Òwe 22:3, 6; Sáàmù 127:4, 5)
-
-
10:45 [11:30] Jèhófà Ni Àpẹẹrẹ Tó Dáa Jù Lọ Tó Bá Dọ̀rọ̀ Ìfaradà (Róòmù 8:22, 23; 15:13; Jákọ́bù 1:2-4)
-
11:15 [12:00] Orin 115 àti Àkókò Ìsinmi
Ọ̀SÁN
-
12:25 [1:00] Fídíò Orin
-
12:35 [1:10] Orin 128
-
12:40 [1:15] ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: À Ń Fara Dà Á Láìka . . .
-
Ìwà Ìrẹ́jẹ (Mátíù 5:38, 39)
-
Ara Tó Ti Ń Dara Àgbà (Aísáyà 46:4; Júúdà 20, 21)
-
Àìpé Tiwa Fúnra Wa (Róòmù 7:21-25)
-
Ìbáwí Tí Kò Bára Dé (Gálátíà 2:11-14; Hébérù 12:5, 6, 10, 11)
-
Àìsàn Ọlọ́jọ́ Pípẹ́ (Sáàmù 41:3)
-
Ikú Èèyàn Wa (Sáàmù 34:18)
-
Inúnibíni (Ìṣípayá 1:9)
-
-
1:55 [2:30] Orin 136 àti Ìfilọ̀
-
2:05 [2:40] ÀWÒKẸ́KỌ̀Ọ́: Ẹ Rántí Aya Lọ́ọ̀tì—Apá Kìíní (Lúùkù 17:28-33)
-
2:35 [3:10] ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Sapá Láti Ní Àwọn Ànímọ́ Tó Máa Jẹ́ Kó O Lè Fara Dà Á
-
Ìgbàgbọ́ (Hébérù 11:1)
-
Ìwà Funfun (Fílípì 4:8, 9)
-
Ìmọ̀ (Òwe 2:10, 11)
-
Ìkóra-Ẹni-Níjàánu (Gálátíà 5:22, 23)
-
-
3:15 [3:50] Bí A Ò Ṣe Ní “Kùnà Lọ́nàkọnà Láé” (2 Pétérù 1:5-10; Aísáyà 40:31; 2 Kọ́ríńtì 4:7-9, 16)
-
3:50 [4:25] Orin 3 àti Àdúrà Ìparí
* Àkókò tó wà nínú àkámọ́ [ ] ni a ó tẹ̀ lé ní Sátidé tó bá jẹ́ ọjọ́ “gbálùúmọ́”