Saturday
“Ẹ máa yọ̀ nínú ìrètí. Ẹ máa ní ìfaradà lábẹ́ ìpọ́njú” —RÓÒMÙ 12:12
ÒWÚRỌ̀
-
8:20 [10:50] Fídíò Orin
-
8:30 [11:00] Orin 44 àti Àdúrà
-
8:40 [11:10] ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Bí Jèhófà Ṣe Ń “Pèsè Ìfaradà àti Ìtùnú” fún . . .
-
Àwọn Aláìlera Àtàwọn Tó Sorí Kọ́ (Róòmù 15:4, 5; 1 Tẹsalóníkà 5:14; 1 Pétérù 5:7-10)
-
Àwọn Aláìní (1 Tímótì 6:18)
-
Àwọn Ọmọ “Aláìníbaba” (Sáàmù 82:3)
-
Àwọn Àgbàlagbà (Léfítíkù 19:32)
-
-
9:50 [12:20] Orin 138 àti Ìfilọ̀
-
10:00 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Kọ́ Ilé Tó Máa Wà Pẹ́ Títí
-
“Ní Ìtẹ́lọ́rùn Pẹ̀lú Àwọn Nǹkan Ìsinsìnyí” (Hébérù 13:5; Sáàmù 127:1, 2)
-
Dáàbò Bo Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ “Ohun Tí Ó Jẹ́ Ibi” (Róòmù 16:19; Sáàmù 127:3)
-
Ẹ Tọ́ Àwọn Ọmọ Yín ‘Ní Ọ̀nà Tí Wọn Yóò Tọ̀’ (Òwe 22:3, 6; Sáàmù 127:4, 5)
-
-
10:45 [12:30] ÌRÌBỌMI: Ẹ Má Ṣe “Bẹ̀rù”! (1 Pétérù 3:6, 12, 14)
-
11:15 [1:00] Orin 79 àti Àkókò Ìsinmi
Ọ̀SÁN
-
12:35 [2:00] Fídíò Orin
-
12:45 [2:10] Orin 126
-
12:50 [2:15] ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ “Àwọn Tí Wọ́n Lo Ìfaradà”
-
Jósẹ́fù (Jẹ́nẹ́sísì 37:23-28; 39:17-20; Jákọ́bù 5:11)
-
Jóòbù (Jóòbù 10:12; 30:9, 10)
-
Ọmọbìnrin Jẹ́fútà (Àwọn Onídàájọ́ 11:36-40)
-
Jeremáyà (Jeremáyà 1:8, 9)
-
-
1:35 [3:00] ÀWÒKẸ́KỌ̀Ọ́: Ẹ Rántí Aya Lọ́ọ̀tì—Apá Kejì (Lúùkù 17:28-33)
-
2:05 [3:30] Orin 111 àti Ìfilọ̀
-
2:15 [3:40] ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Kọ́ Ìfaradà Lára Àwọn Ohun Tí Ọlọ́run Dá
-
Ràkúnmí (Júúdà 20)
-
Igi Orí Òkè (Kólósè 2:6, 7; 1 Pétérù 5:9, 10)
-
Labalábá (2 Kọ́ríńtì 4:16)
-
Ẹyẹ Ilẹ̀ Olótùútù (1 Kọ́ríńtì 13:7)
-
Ẹyẹ Etí Omi (Hébérù 10:39)
-
Igi Bọn-Ọ̀n-Ní (Éfésù 6:13)
-
-
3:15 [4:40] Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Ìfaradà Yín Ń Mú Inú Jèhófà Dùn! (Òwe 27:11)
-
3:50 [5:15] Orin 135 àti Àdúrà Ìparí