Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí

Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí
  1. Kí ni “òfin Kristi”? (Gál. 6:2)

  2. Báwo la ṣe lè mú òfin Kristi ṣẹ nígbà tá a bá dá wà? (1 Kọ́r. 10:31)

  3. Báwo la ṣe lè mú òfin Kristi ṣẹ lẹ́nu iṣẹ́ òjíṣẹ́ wa? (Lúùkù 16:10; Mát. 22:39; Ìṣe 20:35)

  4. Kí ló mú kí òfin Kristi ju Òfin Mósè lọ? (1 Pét. 2:16)

  5. Báwo làwọn tọkọtaya àtàwọn òbí ṣe lè mú òfin Kristi ṣẹ nínú ìdílé wọn? (Éfé. 5:​22, 23, 25; Héb. 5:​13, 14)

  6. Báwo lo ṣe lè mú òfin Kristi ṣẹ ní iléèwé? (Sm. 1:​1-3; Jòh. 17:14)

  7. Báwo la ṣe lè nífẹ̀ẹ́ àwọn èèyàn bí Jésù ṣe nífẹ̀ẹ́ wa? (Gál. 6:​1-5, 10)