Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Má Sọ̀rètí Nù Bó O Ṣe Ń Mú Òfin Kristi Ṣẹ!

Má Sọ̀rètí Nù Bó O Ṣe Ń Mú Òfin Kristi Ṣẹ!

ÒWÚRỌ̀

  • 9:40 [11:30] * Ohùn Orin

  • 9:50 [11:40] Orin 17 àti Àdúrà

  • 10:00 [11:50] Kí Ni Òfin Kristi?

  • 10:15 [12:05] Bá A Ṣe Lè Mú Òfin Kristi Ṣẹ Nígbà Tá A Bá Dá Wà

  • 10:30 [12:20] Bá A Ṣe Lè Mú Òfin Kristi Ṣẹ Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù

  • 10:55 [12:45] Orin 70 àti Ìfilọ̀

  • 11:05 [12:55] Kí Nìdí Tí Òfin Kristi Fi Ju Òfin Mósè Lọ?

  • 11:35 [1:25] Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi

  • 12:05 [1:55] Orin 51

Ọ̀SÁN

  • 1:20 [2:35] Ohùn Orin

  • 1:30 [2:45] Orin 76

  • 1:35 [2:50] Ìrírí

  • 1:45 [3:00] Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́

  • 2:15 [3:30] Bá A Ṣe Lè Mú Òfin Kristi Ṣẹ Nínú Ìdílé

  • 2:30 [3:45] Bá A Ṣe Lè Mú Òfin Kristi Ṣẹ ní Iléèwé

  • 2:45 [4:00] Orin 35 àti Ìfilọ̀

  • 2:55 [4:10] Ẹ Nífẹ̀ẹ́ Ara Yín Bí Jésù Ṣe Nífẹ̀ẹ́ Yín

  • 3:55 [5:10] Orin 13 àti Àdúrà

^ ìpínrọ̀ 3 Àkókò tó wà nínú àkámọ́ [ ] ni a ó tẹ̀ lé ní Sátidé tó bá jẹ́ ọjọ́ “Gbálùúmọ́”