Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2017-2018—Tí Alábòójútó Àyíká Máa Bá Wa Ṣe
Wo ìtòlẹ́sẹẹsẹ àpéjọ àyíká yìí tí a ti máa gbọ́ àsọyé látẹnu alábòójútó àyíká.
Má Sọ̀rètí Nù Bó O Ṣe Ń Ṣe Ohun Tó Dára!
Kí nìdí tó fi ṣòro láti ṣe ohun tó dára, àmọ́ kí ló máa ràn wá lọ́wọ́ láti ṣàṣeyọrí?
Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí
A máa sọ̀rọ̀ nípa àwọn ìbéèrè yìí, a sì máa dáhùn wọn nígbà tí ìtòlẹ́sẹẹsẹ àpéjọ náà bá ń lọ lọ́wọ́.