Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí

Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí
  1. Kí nìdí tó fi ṣòro láti ṣe ohun tó dára? (1 Pét. 5:8; Róòmù 12:2; Róòmù 7:​21-25)

  2. Kí ló túmọ̀ sí láti fúnrúgbìn pẹ̀lú níní ẹran ara lọ́kàn, báwo la ṣe lè yẹra fún ṣíṣe bẹ́ẹ̀? (Gál. 6:8)

  3. Àwọn wo ló yẹ ká máa “ṣe ohun rere sí”? (Gál. 6:10)

  4. Báwo la ṣe lè máa fúnrúgbìn nípa ti ẹ̀mí? (Gál. 6:8)

  5. Kí la máa ká tí a kò bá ṣàárẹ̀? (Gál. 6:9)