Má Sọ̀rètí Nù Bó O Ṣe Ń Ṣe Ohun Tó Dára!
ÒWÚRỌ̀
-
9:30 [11:30] * Ohùn Orin
-
9:40 [11:40] Orin 77 àti Àdúrà
-
9:50 [11:50] Kí Nìdí Tó Fi Ṣòro Láti Ṣe Ohun Tó Dára?
-
10:05 [12:05] Àpínsọ Àsọyé: Má Ṣe Fúnrúgbìn Pẹ̀lú Níní Ẹran Ara Lọ́kàn
-
Máa Fọgbọ́n Lo Ìkànnì Àjọlò
-
Yan Eré Ìnàjú Tó Bójú Mu
-
Kọjú Ìjà sí Ẹ̀mí Ìlara
-
Máa Lépa Ọjọ́ Ọ̀la Tó Fini Lọ́kàn Balẹ̀
-
-
11:05 [1:05] Orin 45 àti Ìfilọ̀
-
11:15 [1:15] Máa Ṣe Ohun Rere sí Gbogbo Èèyàn
-
11:30 [1:30] Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi
-
12:00 [2:00] Orin 63
Ọ̀SÁN
-
1:10 [2:40] Ohùn Orin
-
1:20 [2:50] Orin 127 àti Àdúrà
-
1:30 [3:00] Àsọyé fún Gbogbo Ènìyàn: Báwo La Ṣe Lè Yẹra fún Fífi Ọlọ́run Ṣe Ẹlẹ́yà?
-
2:00 [3:30] Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́
-
2:30 [4:00] Orin 59 àti Ìfilọ̀
-
2:40 [4:10] Àpínsọ Àsọyé: Máa Fúnrúgbìn Nípa Ti Ẹ̀mí
-
Jẹ́ Kó Mọ́ Ẹ Lára Láti Máa Kẹ́kọ̀ọ́
-
Fi Àwọn Ìlànà Bíbélì Darí Ìgbésí Ayé Rẹ
-
“Má Ṣe Jẹ́ Kí Ọwọ́ Rẹ Sinmi”
-
-
3:40 [5:10] Ohun Tá A Máa Ká Tí A Kò Bá Ṣàárẹ̀
-
4:15 [5:45] Orin 126 àti Àdúrà
^ ìpínrọ̀ 3 Àkókò tó wà nínú àkámọ́ [ ] ni a ó tẹ̀ lé ní Sátidé tó bá jẹ́ ọjọ́ “Gbálùúmọ́”