Friday
“Jẹ́ onígboyà àti alágbára gidigidi”—JÓṢÚÀ 1:7
ÒWÚRỌ̀
-
9:20 Fídíò Orin
-
9:30 Orin 110 àti Àdúrà
-
9:40 Ọ̀RỌ̀ ALÁGA: Jèhófà Ló Ń Jẹ́ Ká Ní Ìgboyà Tòótọ́ (Sáàmù 28:7; 31:24; 112:7, 8; 2 Tímótì 1:7)
-
10:10 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Ìdí Tí Àwa Kristẹni Tòótọ́ Fi Nílò Ìgboyà
-
Láti Wàásù (Ìṣípayá 14:6)
-
Láti Máa Jẹ́ Mímọ́ (1 Kọ́ríńtì 16:13, 14)
-
Láti Má Ṣe Dá Sí Ọ̀rọ̀ Òṣèlú (Ìṣípayá 13:16, 17)
-
-
11:05 Orin 126 àti Ìfilọ̀
-
11:15 BÍBÉLÌ KÍKÀ BÍ ẸNI ṢE ERÉ ÌTÀN: “Jẹ́ Onígboyà àti Alágbára Kí O sì Gbé Ìgbésẹ̀”! (1 Kíróníkà 28:1-20; 1 Sámúẹ́lì 16:1-23; 17:1-51)
-
11:45 ‘Ohun Ìjà Yòówù Tí Wọ́n Bá Ṣe sí Ọ Kì Yóò Ṣe Àṣeyọrí’ (Aísáyà 54:17; Sáàmù 118:5-7)
-
12:15 Orin 61 àti Àkókò Ìsinmi
Ọ̀SÁN
-
1:25 Fídíò Orin
-
1:35 Orin 69
-
1:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Ohun Tí Kì Í Jẹ́ Kí Ìgboyà Lágbára Àtohun Tó Ń Jẹ́ Kí Ìgboyà Túbọ̀ Lágbára
-
Àìnírètí àti Ìrètí (Sáàmù 27:13, 14)
-
Ìráhùn àti Ìdúpẹ́ (Sáàmù 27:1-3)
-
Eré Ìnàjú Tí Kò Bójú Mu àti Iṣẹ́ Ìwàásù (Sáàmù 27:4)
-
Ẹgbẹ́ Burúkú àti Ẹgbẹ́ Rere (Sáàmù 27:5; Òwe 13:20)
-
Ọgbọ́n Ayé àti Ìdákẹ́kọ̀ọ́ (Sáàmù 27:11)
-
Iyè Méjì àti Ìgbàgbọ́ (Sáàmù 27:7-10)
-
-
3:10 Orin 55 àti Ìfilọ̀
-
3:20 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Ohun Tí Wọ́n Yááfì; Bí Ọlọ́run Ṣe San Wọ́n Lẹ́san
-
Hananáyà, Míṣáẹ́lì àti Asaráyà (Dáníẹ́lì 1:11-13; 3:27-29)
-
Ákúílà àti Pírísílà (Róòmù 16:3, 4)
-
Sítéfánù (Ìṣe 6:11, 12)
-
-
3:55 “Ẹ Mọ́kànle! Mo Ti Ṣẹ́gun Ayé” (Jòhánù 16:33; 1 Pétérù 2:21, 22)
-
4:15 Àwọn Ọmọ Ogun Kristi Onígboyà (2 Kọ́ríńtì 10:4, 5; Éfésù 6:12-18; 2 Tímótì 2:3, 4)
-
4:50 Orin 22 àti Àdúrà Ìparí