Sunday
“Jẹ́ onígboyà, sì jẹ́ kí ọkàn-àyà rẹ jẹ́ alágbára. Bẹ́ẹ̀ ni, ní ìrètí nínú Jèhófà”—SÁÀMÙ 27:14
ÒWÚRỌ̀
-
9:20 Fídíò Orin
-
9:30 Orin 73 àti Àdúrà
-
9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Àwọn Ohun Tó Máa Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Iwájú Tó Gba Pé Ká Ní Ìgboyà
-
Ìkéde “Àlàáfíà àti Ààbò!” (1 Tẹsalóníkà 5:2, 3)
-
Ìparun Bábílónì Ńlá (Ìṣípayá 17:16, 17)
-
Ìkéde Tó Dà Bí Òkúta Yìnyín (Ìṣípayá 16:21)
-
Gọ́ọ̀gù Ti Ilẹ̀ Mágọ́gù Máa Gbéjà Ko Àwọn Èèyàn Ọlọ́run (Ìsíkíẹ́lì 38:10-12, 14-16)
-
Amágẹ́dọ́nì (Ìṣípayá 16:14, 16)
-
Iṣẹ́ Àtúnkọ́ Ńlá (Aísáyà 65:21)
-
Ìdánwò Ìkẹyìn (Ìṣípayá 20:3, 7, 8)
-
-
11:10 Orin 8 àti Ìfilọ̀
-
11:20 ÀSỌYÉ FÚN GBOGBO ÈNÌYÀN: Báwo Ni Ìrètí Àjíǹde Ṣe Ń Jẹ́ Ká Ní Ìgboyà? (Máàkù 5:35-42; Lúùkù 12:4, 5; Jòhánù 5:28, 29; 11:11-14)
-
11:50 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́
-
12:20 Orin 151 àti Àkókò Ìsinmi
Ọ̀SÁN
-
1:35 Fídíò Orin
-
1:45 Orin 5
-
1:50 FÍÌMÙ: Ìtàn Jónà—Ẹ̀kọ́ Nípa Ìgboyà àti Àánú (Jónà 1-4)
-
2:40 Orin 71 àti Ìfilọ̀
-
2:50 Àwọn Tó Wà Pẹ̀lú Wa Pọ̀ Ju Awọn Tó Wà Lòdì Sí Wa Lọ! (Diutarónómì 7:17, 21; 28:2; 2 Àwọn Ọba 6:16; 2 Kíróníkà 14:9-11; 32:7, 8, 21; Aísáyà 41:10-13)
-
3:50 Orin Ìparí àti Àdúrà