Friday
“Ẹ máa yọ̀ nígbà gbogbo nínú Olúwa. Lẹ́ẹ̀kan sí i, mo sọ pé, Ẹ máa yọ̀!”—Fílípì 4:4
ÀÁRỌ̀
-
9:20 Fídíò Orin
-
9:30 Orin 111 àti Àdúrà
-
9:40 Ọ̀RỌ̀ ALÁGA: Ìdí Tí Jèhófà Fi Jẹ́ “Ọlọ́run Aláyọ̀” (1 Tímótì 1:11)
-
10:15 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Kí Lá Jẹ́ Kó O Láyọ̀?
-
• Jẹ́ Kí Ohun Díẹ̀ Tẹ́ Ẹ Lọ́rùn (Oníwàásù 5:12)
-
• Ẹ̀rí Ọkàn Tó Mọ́ (Sáàmù 19:8)
-
• Iṣẹ́ Tó Ń Fini Lọ́kàn Balẹ̀ (Oníwàásù 4:6; 1 Kọ́ríńtì 15:58)
-
• Àwọn Ọ̀rẹ́ Tòótọ́ (Òwe 18:24; 19:4, 6, 7)
-
-
11:05 Orin 89 àti Ìfilọ̀
-
11:15 BÍBÉLÌ KÍKÀ BÍ ẸNI ṢE ERÉ ÌTÀN: ‘Jèhófà Mú Kí Wọ́n Máa Yọ̀’ (Ẹ́sírà 1:1–6:22; Hágáì 1:2-11; 2:3-9; Sekaráyà 1:12-16; 2:7-9; 3:1, 2; 4:6, 7)
-
11:45 Máa Yọ̀ Nítorí Àwọn Iṣẹ́ Ìgbàlà Jèhófà (Sáàmù 9:14; 34:19; 67:1, 2; Àìsáyà 12:2)
-
12:15 Orin 148 àti Àkókò Ìsinmi
Ọ̀SÁN
-
1:30 Fídíò Orin
-
1:40 Orin 131
-
1:45 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Jẹ́ Kí Ayọ̀ Wà Nínú Ìdílé Rẹ
-
• Ẹ̀yin Ọkọ, Ẹ Máa Yọ̀ Pẹ̀lú Ìyàwó Yín (Òwe 5:18, 19; 1 Pétérù 3:7)
-
• Ẹ̀yin Aya, Ẹ Máa Yọ̀ Pẹ̀lú Ọkọ Yín (Òwe 14:1)
-
• Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Máa Yọ̀ Pẹ̀lú Àwọn Ọmọ Yín (Òwe 23:24, 25)
-
• Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Máa Yọ̀ Pẹ̀lú Àwọn Òbí Yín (Òwe 23:22)
-
-
2:50 Orin 135 àti Ìfilọ̀
-
3:00 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Àwọn Ohun Tí Jèhófà Dá Fi Hàn Pé Ó Fẹ́ Ká Máa Yọ̀
-
• Àwọn Òdòdó Tó Rẹwà (Sáàmù 111:2; Mátíù 6:28-30)
-
• Oúnjẹ Aládùn (Oníwàásù 3:12, 13; Mátíù 4:4)
-
• Àwọ̀ Mèremère (Sáàmù 94:9)
-
• Ara Èèyàn (Ìṣe 17:28; Éfésù 4:16)
-
• Ohùn Tó Ń Tuni Lára (Òwe 20:12; Àìsáyà 30:21)
-
• Àwọn Ẹranko Àgbàyanu (Jẹ́nẹ́sísì 1:26)
-
-
4:00 Kí Nìdí Tí ‘Àwọn Tó Ń Wá Àlàáfíà Fi Máa Ń Láyọ̀’? (Òwe 12:20; Jémíìsì 3:13-18; 1 Pétérù 3:10, 11)
-
4:20 Àjọṣe Tímọ́tímọ́ Pẹ̀lú Jèhófà Lohun Tó Ń Fúnni Láyọ̀ Tó Ga Jù Lọ! (Sáàmù 25:14; Hábákúkù 3:17, 18)
-
4:55 Orin 28 àti Àdúrà Ìparí