A N Waasu A si N Koni Kari Aye
KÁRÍ AYÉ
-
ILẸ̀ 239
-
IYE AKÉDE 8,201,545
-
ÀRÒPỌ̀ WÁKÀTÍ TÁ A FI WÀÁSÙ 1,945,487,604
-
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ 9,499,933
NÍ APÁ YÌÍ
Afirika
Ka awon ohun pataki to sele lenu ise ikonilekoo Bibeli ti a se lorile-ede Angola, Kongo (Kinshasa), Gana, Naijiria ati South Africa lodun 2014.
Awon Ile Amerika
Ka awon ohun pataki to sele lenu ise ikonilekoo Bibeli ta a se lorile-ede Ajentina, Brazil, Haiti, Paraguay ati Suriname lodun 2014.
Esia ati Aarin Gbungbun Ila Oorun Aye
Ka nipa ise ikonilekoo Bibeli ti a n se lorile-ede Indonesia, Mongolia, Philippines atawon orile-ede mii nile Esia lodun 2014.
Yuroopu
Ka awon ohun pataki to sele lenu ise ikenilekoo Bibeli ta a se lorile-ede Bogeria, Finland, Jamani, Romania, Rosia, Sipeeni ati Sweden lodun 2014.
Agbegbe Oceania
Ka awon ohun pataki to sele lenu ise ikonilekoo Bibeli wa lorile-ede Kiribati, awon Erekusu Marshall, Papua New Guinea ati Vanuatu lodun 2014.