Atọ́ka Àwọn Àpèjúwe (Àkàwé)
Nọ́ńbà kọ̀ọ̀kan dúró fún orí tí àpèjúwe náà wà.
afúnrúgbìn 43
afúnrúgbìn tó sùn 43
àgbébọ̀ adìyẹ ń kó àwọn ọmọ rẹ̀ jọ 110
agbowó orí àti Farisí 94
àgùntàn àti ewúrẹ́ 114
àgùntàn tó sọ nù 63
àjàrà tòótọ́ 120
àlìkámà àti èpò 43
apẹja èèyàn 22
ará Samáríà tó jẹ́ aládùúgbò rere 73
àwọ̀n 43
àwọn ẹyẹ àti òdòdó lílì 35
àwọn méjì tó jẹ gbèsè 40
àwọn òṣìṣẹ́ ọgbà àjàrà 97
àwọn ọmọ kéékèèké nínú ọjà 39
àwọn tó kọ ìkésíni síbi àsè 83
àwọn tó ń dáko pa ọmọ ẹni tó loko 106
àwọn tó ń dáko, tí wọ́n sì pààyàn 106
ayẹyẹ ìgbéyàwó ọba 107
dírákímà tó sọ nù 85
èso lórí ilẹ̀ tó yàtọ̀ síra 43
ẹ̀mí àìmọ́ tó pa dà wá 42
ẹni tó fẹ́ kọ́ ilé gogoro 84
ẹni tó fọwọ́ lé ohun ìtúlẹ̀ 65
ẹni tó rí dírákímà tó sọ nù 85
ẹnubodè tóóró 35
ẹrú olóòótọ́ àti olóye 111
ẹrú tí kò dárí jini 64
ẹrú tó dé láti oko 89
ẹrú tó ń dúró de ọ̀gá rẹ̀ pé kó dé 78
hóró àlìkámà kú, ó sì so èso 103
hóró músítádì, ìgbàgbọ́ 89
hóró músítádì, Ìjọba 43
igi ọ̀pọ̀tọ́ 79
ilé tí wọ́n kọ́ sórí àpáta 35
ìpìlẹ̀ ilé 35
ìríjú aláìṣòdodo 87
ìríjú olóòótọ́ 78
ìṣúra tí a fi pa mọ́ sínú pápá 43
ìwúkàrà àwọn Farisí 58
ìwúkàrà tí wọ́n pọ̀ mọ́ ìyẹ̀fun 43
iyọ̀ ayé 35
jókòó síbi tó lọ́lá jù 83
mínà 100
ojú abẹ́rẹ́ 96
Olùṣọ́ àgùntàn àtàtà 80
opó kan àti adájọ́ kan 94
ó wu baba láti fúnni ní nǹkan 35
ọba fagi lé gbèsè ńlá tẹ́nì kan jẹ ẹ́ 64
ọba ronú kó tó lọ sójú ogun 84
ọkùnrin ọlọ́rọ̀ àti Lásárù 88
ọkùnrin ọlọ́rọ̀ tó kọ́ ilé ìkẹ́rùsí 77
ọmọ méjì tí wọ́n rán lọ ṣiṣẹ́ nínú ọgbà àjàrà 106
ọmọ onínàákúnàá 86
ọmọ tó sọ nù 86
ọ̀rẹ́ kan tí kò yéé bẹ̀bẹ̀ 74
pe àwọn aláìní síbi àsè 83
péálì kan tó níye lórí gan-an 43
péálì níwájú àwọn ẹlẹ́dẹ̀ 35
pòròpórò nínú ojú arákùnrin 35
ràkúnmí gba ojú abẹ́rẹ́ kọjá 96
rán aṣọ tuntun mọ́ aṣọ tó ti gbó 28
sẹ́ kòkòrò tín-tìn-tín, gbé ràkúnmí mì 109
tálẹ́ńtì 113
wáìnì tuntun, àpò awọ tó ti gbó 28
wọ́n san dínárì fáwọn òṣìṣẹ́ 97
wúńdíá mẹ́wàá 112
ATỌ́KA ÀWỌN ÀPÓTÍ