APÁ 2
Ìbẹ̀rẹ̀ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Jésù
‘Wò ó, Ọ̀dọ́ Àgùntàn Ọlọ́run tó kó ẹ̀ṣẹ̀ ayé lọ.’—Jòhánù 1:29
NÍ APÁ YÌÍ
ORÍ 14
Jésù Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Ní Ọmọ Ẹ̀yìn
Kí ló jẹ́ kó dá àwọn ọmọ ẹ̀yìn mẹ́fà tí Jésù kọ́kọ́ ní lójú pé àwọn ti rí Mèsáyà náà?
ORÍ 15
Jésù Ṣe Iṣẹ́ Ìyanu Àkọ́kọ́
Jésù jẹ́ kí ìyá rẹ̀ mọ̀ pé Baba òun ọ̀run ló ń darí òun báyìí, kì í ṣe ìyá òun.
ORÍ 16
Jésù Ní Ìtara fún Ìjọsìn Tòótọ́
Òfin Ọlọ́run gba àwọn èèyàn láyè láti ra ẹran tí wọ́n máa fi rúbọ ní Jerúsálẹ́mù, kí ló wá dé tí inú fi bí Jésù sí àwọn oníṣòwò tó wà nínú tẹ́ńpìlì?
ORÍ 18
Jòhánù Ń Dín Kù, Àmọ́ Jésù Ń Pọ̀ Sí I
Àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jòhánù Arinibọmi ń jowú, bó tilẹ̀ jẹ́ pé Jòhánù ò jowú.
ORÍ 19
Jésù Kọ́ Obìnrin Ará Samáríà Kan Lẹ́kọ̀ọ́
Jésù sọ ohun kan tí kò sọ fún ẹnì kankan rí fún obìnrin náà.