Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

APÁ 4 • ÌṢE 13:1–14:28

“Ẹ̀mí Mímọ́ Rán Wọn Jáde”

“Ẹ̀mí Mímọ́ Rán Wọn Jáde”

ÌṢE 13:4

Nínú apá yìí, a máa sọ̀rọ̀ nípa ìrìn àjò míṣọ́nnárì àkọ́kọ́ tí àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù lọ. Ó fẹ́rẹ̀ẹ́ jẹ́ pé gbogbo ìlú tí Pọ́ọ̀lù dé ni wọ́n ti ṣenúnibíni sí i. Síbẹ̀, ẹ̀mí mímọ́ ń ran Pọ́ọ̀lù lọ́wọ́ kó lè máa bá a lọ láti máa wàásù, ó sì ń dá àwọn ìjọ tuntun sílẹ̀. Bá a ṣe ń kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìtàn tó gbádùn mọ́ni yìí, ó dájú pé ó máa wu àwa náà pé ká fìtara ṣe iṣẹ́ òjíṣẹ́ wa.